B.O.S (@tunde_sosina) 's Twitter Profile
B.O.S

@tunde_sosina

Entrepreneur (Consumer Aggregate, Digital Marketing), Management Consult, Emotional Intelligence Manager, Teacher and a disciple of Jesus Christ...YNWA

ID: 2158398478

calendar_today29-10-2013 09:42:34

28,28K Tweet

5,5K Followers

5,5K Following

B.O.S (@tunde_sosina) 's Twitter Profile Photo

BABA jo ranti mi Ni ‘ile Mimo Ioke Jo gba mi ki nje tire S'ile Mimo loke Egbe: Oluwa ranti mi Oluwa ranti mi Gbat'O ba de joba Re Oluwa ranti mi 2. Elese jo ronu K‘akoko to koj Akoko koja f’ole To wa lowo osi Egbe: Oluwa ranti mi... 🎹🎤🎼🎧🥁🎺🎸🎷🪘

B.O.S (@tunde_sosina) 's Twitter Profile Photo

OLORUN Eleda/jowo sunmo wa Awa omo Re de/lati juba Re Ran Serafu t'orun/ati Kerubu Lati wa ba wa pe/Iati jo yin O 2. Baba Olubukun/bukun wa loni Je k'ipade oni/le mu eso wa Je ki omo 'mole/to wa l'okunkun Wa sinu imole/lati ri ‘gbala 🎹🎤🎼🎧🥁🎺🎸🎷🪘

B.O.S (@tunde_sosina) 's Twitter Profile Photo

OBA TI ki ye Majemu F'ore ofe Re fun wa Majemu ti a ba O da Ki awa ko le mu se Egbe: Nitori iku Messaiah Jowo ko sanu fun wa. 2ce 2. Oba Mimo Oba Ogo Wo l‘awa nfi iyin fun Kerubu ati Serafu S'ope odun titun yi Egbe: Nitori iku Messaiah... 🎹🎤🎼🎧🥁🎺🎸🎷🪘

DemoBabaA (@demobabaa) 's Twitter Profile Photo

B.O.S "Know therefore that the LORD your God is God; he is the faithful God, keeping his covenant of love to a thousand generations of those who love him and keep his commandments." Deut. 7:9

B.O.S (@tunde_sosina) 's Twitter Profile Photo

IRAPADA; ltan iyanu Ni ayo fun o at'emi Pe Jesu ti ra idariji O san gbese na lori ‘gi Egbe: A! ‘wo elese gba eyi gbo Gba ihin otito na gbo Gbeke l 'eni to ku Iori 'gi To mu igbala wa fun o 2. Gbani Olorun nisisiyi Segun agbar'ese fun wa 'Tori on yio gba enito wa Ki yio si ta o..

B.O.S (@tunde_sosina) 's Twitter Profile Photo

BABA jo gbo temi Mo wole lese Re ‘Wo to nwosan to ndariji Jowo gbadura wa 2. Olorun Oluwa Jehofa Oba mi ‘Wo to tedo sinu ‘mole Ajuba O’ko Re 3. Tali oba ti aiye? Jesu Emmanuel Gbongbo Jesse Eni ‘Yanu Ran ‘ranwo Re si mi 🎹🎤🎼🎧🥁🎺🎸🎷🪘

B.O.S (@tunde_sosina) 's Twitter Profile Photo

IGBALA ni, igbala ni Awa elese nfe Nitori ninu buburu T‘a se l‘awa nsegbe 2. lse owo wa ti a nse O nwi nigbagbogbo Pe, igbala ko si nibe Ise ko le gba ni 3. Awa nsebo, awa nrubo A nkorin, a si njo Sugbon a ko ri igbala Ninu gbogbo wonyi 🎹🎤🎼🎧🥁🎺🎸🎷🪘

B.O.S (@tunde_sosina) 's Twitter Profile Photo

GBANGBA l‘oju Re Olorun S’Ohun gbogbo ta nse T'osan t'oru bakanna ni L'oju Oluwa wa 2. Ko s’ese kan ti a le da Ko s’oro t'a le so Ti ko si ninu iwe Re Fun iranti gbogbo 3. Ese ole, ese iro Ese aiforiji Ese ka soro eni lehin Baba dariji wa 🎹🎤🎼🎧🥁🎺🎸🎷🪘

DemoBabaA (@demobabaa) 's Twitter Profile Photo

B.O.S "Nothing in all creation is hidden from God’s sight. Everything is uncovered and laid bare before the eyes of him to whom we must give account." Hebrews 4:13

DemoBabaA (@demobabaa) 's Twitter Profile Photo

B.O.S "Kò sí ẹ̀dá kan tí kò farahàn níwájú rẹ̀, ṣùgbọ́n ohun gbogbo ni ó wà níhòhò tí a sì ṣípáyà fún ojú rẹ̀, níwájú ẹni tí àwa yóò jíyìn." Heberu 4:13

B.O.S (@tunde_sosina) 's Twitter Profile Photo

OBA awon eni Mimo T'o mo ye awon ‘rawo Opo enit' Eda gbagbe Wa yika ite Re lati Egbe: Mimo Mimo, Mimo Mimo, Mimo Mimo Lo ye O Iwo I'a ba ma f' iyin fun Olorun, Edumare 2. Enit' o wa ninu ‘mole T oju enikan ko ri Mose ri akehinsi Re Oju Mose ran b'orun Egbe: Mimo Mimo.. 🎹🎼

B.O.S (@tunde_sosina) 's Twitter Profile Photo

Mimo, Mimo, Mimo Olodumare Ni kutukutu ni ‘wo o gbo orin wa Mimo, Mimo, Mimo! Oniyonu julo Ologo meta lai Olubukun 2. Mimo, Mimo, Mimo awon t'orun nyin Nwon nfi ade wura won lele y'ite ka Kerubim Serafim nwole niwaju Re Wo to ti wa to si wa titi lai 🎹🎼🎧🥁🎺🎸🎷🪘