Bọ́láńlé oní story 🖋️ (@tyewoolove) 's Twitter Profile
Bọ́láńlé oní story 🖋️

@tyewoolove

Ghostwriter. Storyteller. Culture Curator. I tell Yorùbá & African stories that matter—on stage, screen, and in books. Let’s keep our heritage alive.

ID: 1143094620064235520

linkhttps://youtu.be/e741uue1RC8?si=BHzNYfS_955xe1Nx calendar_today24-06-2019 09:52:49

115,115K Tweet

67,67K Followers

3,3K Following

Bọ́láńlé oní story 🖋️ (@tyewoolove) 's Twitter Profile Photo

Ìwúre t'òní Ẹ máa wí tẹ̀lé mi Ìyà kò ní jẹ mí Ọ̀tá kò ní rídìí mi Mi 'ò ní ṣòfò Mi 'ò ní ṣánkú Ire máa jẹ́ tèmi Aláàánú á wá mi rí Mi 'ò ní tọrọ jẹ Mi 'ò ní w'àkísà Ojúmọ́ rere ló mọ́ wa lónìí o.