Adéjọké̩ Ẹwàèdè (@adejokeewaede) 's Twitter Profile
Adéjọké̩ Ẹwàèdè

@adejokeewaede

Yorùbá dùn! I am an African art revitalist, protection&promotion of yorùbá language is my destined assignment.Our cultural heritage mustn’t go into extinction.

ID: 766668537884733440

linkhttps://bit.ly/3DmwpsH calendar_today19-08-2016 16:09:58

1,1K Tweet

16,16K Takipçi

40 Takip Edilen

Man of Letters. (@letter_to_jack) 's Twitter Profile Photo

Ẹyin ọmọ kaarọ o jiire… We have selected a date for our quarterly Tweet-In-Yoruba Day. The date for the next #YorubaDun is Thursday, June 5th, 2025. 3 days before ILEYA. RT if you’re exited!

Adéjọké̩ Ẹwàèdè (@adejokeewaede) 's Twitter Profile Photo

Ọmọ rere l'ó n di àgbà rere, ọmọ burúkú l'ó n di àgbà burúkú... A kú àyájó̩ àwọn èwe, ó tọ́ k'á ṣ'ìké̩ ọmọ, ṣùgbó̩n a ò gbọdọ̀ fa ọwó̩ ìbáwí s'é̩yìn. Èdùmàrè á dá gbogbo ọmọ sí fún wa. Àṣẹ

Ọmọ rere l'ó n di àgbà rere, ọmọ burúkú l'ó n di àgbà burúkú...

A kú àyájó̩ àwọn èwe, ó tọ́ k'á ṣ'ìké̩ ọmọ, ṣùgbó̩n a ò gbọdọ̀ fa ọwó̩ ìbáwí s'é̩yìn. Èdùmàrè á dá gbogbo ọmọ sí fún wa. Àṣẹ
Adéjọké̩ Ẹwàèdè (@adejokeewaede) 's Twitter Profile Photo

Káàbọ̀ sí inú oṣù kẹfà, l'óṣù ẹ̀fà yìí ayé rẹ ò níí fàya, òùnfà tíí fa ire, á fa ire wá fún gbogbo wa l'áṣẹ èdùmàrè 🙏

Adéjọké̩ Ẹwàèdè (@adejokeewaede) 's Twitter Profile Photo

Afú’rúgbìn n retí ọ̀pọ̀, ẹni tí ò ki èèbù b'o̩lẹ̀, kò leè gbúro odó. A seed that is not prepared to go beneath the ground, would never germinate into a fruit. Ire o

Adéjọké̩ Ẹwàèdè (@adejokeewaede) 's Twitter Profile Photo

TO GOD BE THE GLORY! Bí kìí bá ṣe pé olúwa kọ́ ilé náà, àwọn òṣíṣẹ̀ n ṣe l'ásan. Èdùmàrè ṣè èyí fún mi t'ayọ èrò. Welcome to Ẹwàèdè cultural centre..

Adéjọké̩ Ẹwàèdè (@adejokeewaede) 's Twitter Profile Photo

Ipá ènìyàn kò tó, Look unto God not your fellow human, bí èdùmàrè kò bá rán wọn sí ẹ, wọn ò ní iṣé̩ tí wó̩n fé̩ jé̩ fún ẹ. Ire o!

Adéjọké̩ Ẹwàèdè (@adejokeewaede) 's Twitter Profile Photo

Iná njó, ògiri ò sá, pápá n jó ìgbẹ́ ò m'ira. Mo yọ̀ fún ẹ, mo yọ̀ fún ara mi, l'áké m'àjó m'àjòjò l'ọ́fà, ọmọ akin tí n f'o̩lá w'e̩wó̩, akọni tí n f'adé rera! Olúwadámiláré, alàgbà tí ò gbàgbàkugbà,ẹ kú ọdún, ẹkú ìyèdún, èdùmàrè ò ní fi Èyí ṣ'òpin oore. Have fun bro

Iná njó, ògiri ò sá, pápá n jó ìgbẹ́ ò m'ira. Mo yọ̀ fún ẹ, mo yọ̀ fún ara mi, l'áké m'àjó m'àjòjò l'ọ́fà, ọmọ akin tí n f'o̩lá w'e̩wó̩, akọni tí n f'adé rera!
Olúwadámiláré, alàgbà tí ò gbàgbàkugbà,ẹ kú ọdún, ẹkú ìyèdún, èdùmàrè ò ní fi Èyí ṣ'òpin oore. Have fun bro
Adéjọké̩ Ẹwàèdè (@adejokeewaede) 's Twitter Profile Photo

T’ẹni nt'ẹni! Our cultural traditions and practices are what make us unique as a people, reflecting our history, values, and beliefs, shaping our identity in the world.

T’ẹni nt'ẹni!
Our cultural traditions and practices are what make us unique as a people, reflecting our history, values, and beliefs, shaping our identity in the world.
Adéjọké̩ Ẹwàèdè (@adejokeewaede) 's Twitter Profile Photo

Ogún ọdún ní ilé onílé, ọgbọ̀n oṣù lé̩é̩dẹ̀ ẹlé̩ẹ̀dẹ̀,ààrè ni ààrè yíò máa jẹ́. The first step towards EMANCIPATION is self discovery & recognition,it is important that we begin to tell our stories by ourselves,in D language we understand &approach relatable to us.

Ogún ọdún ní ilé onílé, ọgbọ̀n oṣù lé̩é̩dẹ̀ ẹlé̩ẹ̀dẹ̀,ààrè ni ààrè yíò máa jẹ́.
The first step towards EMANCIPATION is self discovery & recognition,it is  important that we begin to tell our stories by ourselves,in D language we understand &approach relatable to us.
Man of Letters. (@letter_to_jack) 's Twitter Profile Photo

We begin again this evening at the newest fun place in Abeokuta (Ita Faaji by Adéjọké̩ Ẹwàèdè.) Oluwa sọ wa dele layọ.. Ma jẹ ki wọn kowa mọ ilẹ laarọ ọla nitori a muti yo sinu gutter.🙏

Adéjọké̩ Ẹwàèdè (@adejokeewaede) 's Twitter Profile Photo

Bí iná kò bá ní awo, kò lè fo odò. That they listen to you doesn’t mean they CARE, sometimes all they want is a topic to discuss with their other FRIENDS. Ire o

Adéjọké̩ Ẹwàèdè (@adejokeewaede) 's Twitter Profile Photo

Adirebyibile is coming to Houston for NBC trade exhibition, get ready to enjoy an exciting shopping experience. See fliers for more details❤️

Adéjọké̩ Ẹwàèdè (@adejokeewaede) 's Twitter Profile Photo

A kìí dò̩bálẹ̀ ká ni iná l'ójú. An internationally humble person humbles himself even before those who should be humbled by his presence. Ire o!

Adéjọké̩ Ẹwàèdè (@adejokeewaede) 's Twitter Profile Photo

The craft of Àdìrẹ is more than fabric it is my inheritance. I could not stand by and watch it fade into obscurity. Each piece of Àdìrẹ tells a story woven in tradition, dyed in resilience, and passed through the hands of generations. #Adire #PreserveTheCraft #houston

Adéjọké̩ Ẹwàèdè (@adejokeewaede) 's Twitter Profile Photo

Welcome to the second half of the year, Àwùjẹ̀ ni ìdàjì orí, ìdòdò ni ìdajì ara, ìdajì t'ó kù nínú ọdún yìí, a ò níí lòó nínú ìnira l'áṣẹ èdùmàrè 🙏

Adéjọké̩ Ẹwàèdè (@adejokeewaede) 's Twitter Profile Photo

Àdìrẹ is SACRED It is not just a fabric. Do your businesses, print as many beautiful designs as you wish, BUT take àdirẹ designs off your machines. Ire o! #adire #originaladire #indigenous #notoprintefadiredesigns