
Mr Tom
@iamtommivill
🔲Humanity Preacher 🔲Award Winning #YorubaProverbs Professor 🔲The Anointed Entertainer 🔲90% Yoruba Contents
ID: 2325620463
05-02-2014 09:31:07
129,129K Tweet
23,23K Followers
13,13K Following



Ẹ kú ayẹyẹ ọjọ́ ìbí arẹwà arábìnrin Tóbilọbá Àdùkẹ́ Titóbilóba Àdùkẹ́ 🎂🎊 Ọlọ́run yóò bùkún yín lọpọlọpọ.








Ẹ kú ayẹyẹ ọjọ́ ìbí arẹwà arábìnrin Ṣíṣí Olójú Edé SisiolojuedeCooks🦐. Ilẹ̀kùn ayọ̀ yóò ṣí fún ní orúkọ Ọlọ́run.🎊🎊🎂🎂

Ẹ kú ayẹyẹ ọjọ́ ìbí arẹwà arábìnrin sealestial🌊being💜 🎂🎊🎂🎊. Elédùmarè yóò bù ọlá fún yín lọpọlọpọ.


Ẹ kú ayẹyẹ ọjọ́ ìbí arákùnrin Crownfit19 🎊🎂🎂 Irè àti ayọ̀ yóò má báyìn gbé lọ́jọ́ gbogbo




