O R I A (@generaloria) 's Twitter Profile
O R I A

@generaloria

X

ID: 719551576277434369

linkhttps://youtu.be/aQlMdFjqCSY calendar_today11-04-2016 15:43:59

3,3K Tweet

282 Followers

247 Following

Olúyẹmí Fásípè AICMC (@yemiefash) 's Twitter Profile Photo

EFCC that lied there was a “yahoo party” going on in Akure the night they invaded those clubs. I knew they would find a way to profile that Anambra guy a yahoo boy.

Mr Tom (@iamtommivill) 's Twitter Profile Photo

Aláàánú láti Gúsù Aláàánú láti Àríwá Aláàánú láti Ìwọ-òrun Aláàánú láti Ìlá-òrun Aláàánú ni arìn gbùngbùn Gbogbo wọn á fí àánú àti ìrànlọwọ ńlá wá èmi àti ìwọ rí ní áìpẹ́ 🤲🏽

Mr Tom (@iamtommivill) 's Twitter Profile Photo

Gbọ́mi dá dá, Bí oṣù yìí ṣe ń parí, Ìbánujẹ rẹ parí 🤲🏽 Ẹkùn rẹ parí 🤲🏽 Àìní rẹ parí 🤲🏽 Ǹjẹ́ a rí ẹni tí ó ń ṣe Àmín?

Bọ́láńlé oní story 🖋️ (@tyewoolove) 's Twitter Profile Photo

Ìwúre t'òní Dídùn dídùn là ńbá ilé olóyin Ayé wa máa dùn j'oyin lọ Gbogbo igi tí elégbèje bá lù dídún ni í dún. Báa bá ṣe ńlùú lọ́ oṣù yìí, á máa dún fún wa o. Láṣẹ Èdùmàrè

Ademọ́lá. (@ogbenidemola) 's Twitter Profile Photo

African traditional religion is the only religion in the world that never went to war to force its beliefs on anyone, anywhere. Yet, those who colonized the entire world call Africa backward.