Banks Tweet (@bankdavies) 's Twitter Profile
Banks Tweet

@bankdavies

Akápò Ifá

ID: 858783195143303168

calendar_today30-04-2017 20:40:43

6,6K Tweet

580 Followers

957 Following

Banks Tweet (@bankdavies) 's Twitter Profile Photo

ح-م صن 🤍 olúwo jògbòdó òrúnmìlà Majority of you are just so DUMB and F00LISH. Qu’ran is just a Story Book and a Text for IMPERIALISM. No Healing references or Prayers it’s just to Kīll and Steal what’s not urs. (Maybe it’s the Auto-Tune that’s deceiving y’all) 1/2

Banks Tweet (@bankdavies) 's Twitter Profile Photo

Àbọrú Àbọyè Àbọṣíṣẹ Gbogbo Ìṣòwò Ọ̀pẹ̀... 🌴🌴🌴 A KÚ Ọ̀ṢẸ̀ IFÁ Òní.. “Òjò Iré Gbogbo ni’lé Akápò” 🌱

Àbọrú Àbọyè Àbọṣíṣẹ Gbogbo Ìṣòwò Ọ̀pẹ̀... 🌴🌴🌴

A KÚ Ọ̀ṢẸ̀ IFÁ Òní..

“Òjò Iré Gbogbo ni’lé Akápò” 🌱
Banks Tweet (@bankdavies) 's Twitter Profile Photo

Yahweh Children & Allah Children are fighting. :)🌚 Dear Abrahamic Adherent in Nigeria this is the time to support your people.

Banks Tweet (@bankdavies) 's Twitter Profile Photo

Olúpẹrẹgẹdẹ Awo ojú Adífá fún Ojú Ojú ń lọ rèé dó obìnrin òde Njẹ́ ojúmọ́ mọ lónìí o Olúpẹrẹgẹdẹ ìwọ l’Awo ojú Ojúmọ́ Owó, Aya rere/Ọkọ rere Olúpẹrẹgẹdẹ ìwọ l’Awo ojú Ojúmọ́ Iré Gbogbo lóde Ìsàlú ayé Olúpẹrẹgẹdẹ ìwọ l’Awo ojú “Ojúmọ́ Iré o” 🌱

Olúpẹrẹgẹdẹ Awo ojú
Adífá fún Ojú
Ojú ń lọ rèé dó obìnrin òde
Njẹ́ ojúmọ́ mọ lónìí o
Olúpẹrẹgẹdẹ ìwọ l’Awo ojú
Ojúmọ́ Owó, Aya rere/Ọkọ rere
Olúpẹrẹgẹdẹ ìwọ l’Awo ojú
Ojúmọ́ Iré Gbogbo lóde Ìsàlú ayé
Olúpẹrẹgẹdẹ ìwọ l’Awo ojú

“Ojúmọ́ Iré o” 🌱
Bennylee (@itsbennylee) 's Twitter Profile Photo

Our Lekki Lagos Temple is 70% Complete ✔️👏 In the very heart of Lagos, Isẹ̀ṣe will rise and thrive not just here, but across all Yorùbáland. This is a sacred rebirth, a revival of truth long buried by foreign noise. We’re coming for the bad eggs — yes — but for now, our

Banks Tweet (@bankdavies) 's Twitter Profile Photo

Àbọrú Àbọyè Àbọṣíṣẹ Gbogbo Ìṣòwò Ọ̀pẹ̀...🌴🌴🌴 A Kú Ọ̀ṢẸ̀ IFÁ Òní.. "Ìlẹ̀kẹ̀ to bá ti já ó d’ọwọ́ òwú ẹ̀ ran Gbogbo òun tí àwa rò ó di ọwọ́ IFÁ" ÀṢẸ si gbogbo Ìwúre waa. 🪴

Àbọrú Àbọyè Àbọṣíṣẹ Gbogbo Ìṣòwò Ọ̀pẹ̀...🌴🌴🌴

A Kú Ọ̀ṢẸ̀ IFÁ Òní..

"Ìlẹ̀kẹ̀ to bá ti já ó d’ọwọ́ òwú ẹ̀ ran
Gbogbo òun tí àwa rò ó di ọwọ́ IFÁ"

ÀṢẸ si gbogbo Ìwúre waa. 🪴