YorubaNationNews(@Yorubanationews) 's Twitter Profileg
YorubaNationNews

@Yorubanationews

News and Updates About Yoruba Nation

ID:1371914516984905728

calendar_today16-03-2021 20:01:48

6,7K Tweets

1,0K Followers

141 Following

YorubaNationNews(@Yorubanationews) 's Twitter Profile Photo

ÌRÒYÌN:

Ilé ejó da ejó fún Bobrisky tí wón sì jùú sí èwòn
osù méfà fún èsè sise owó naira básubàsu

Nation ews Nation

ÌRÒYÌN: Ilé ejó da ejó fún Bobrisky tí wón sì jùú sí èwòn osù méfà fún èsè sise owó naira básubàsu #YorubaNationews #YorubaNation #Yoruba #News
account_circle
YorubaNationNews(@Yorubanationews) 's Twitter Profile Photo

ÌRÒYÌN:

Eré alárinrin pèlú àsà ilè Yoruba láti owó
Arábìnrin òsèré Eniola Ajao ti jáde sí
Gbogbo cinema pàtàpàta.

Nation ews Nation

ÌRÒYÌN: Eré alárinrin pèlú àsà ilè Yoruba láti owó Arábìnrin òsèré Eniola Ajao ti jáde sí Gbogbo cinema pàtàpàta. #YorubaNationews #YorubaNation #Yoruba #News
account_circle
YorubaNationNews(@Yorubanationews) 's Twitter Profile Photo

ÌRÒYÌN:

Ìjoba TINUBU ti fi owó kun owó atégûn ìdáná tí àwon
Tí npèsé Iná fún ará ìlú ma nlo láti fi pèsé Iná won.

Nation ews Nation

ÌRÒYÌN: Ìjoba TINUBU ti fi owó kun owó atégûn ìdáná tí àwon Tí npèsé Iná fún ará ìlú ma nlo láti fi pèsé Iná won. #YorubaNationews #YorubaNation #Yoruba #News
account_circle
YorubaNationNews(@Yorubanationews) 's Twitter Profile Photo

ÌRÒYÌN:

Alfa se ÀDÚRÀ fún àwon tí ó bá lówó nínú ikú Mohbad, ní Àmín sòro se fún àwon tí nbè lórí ìjókòó.

Nation ews Nation

account_circle
YorubaNationNews(@Yorubanationews) 's Twitter Profile Photo

ÌRÒYÌN:

Abubakar kabir Abubakar tí o je okàn lára awon òsìsé Ìgbìmò asòfin fun ìlú Bichi ni ìpínlè Kano ni ó npín ìresì fún àwon ará ìlú rè.

Nation ews Nation

account_circle
YorubaNationNews(@Yorubanationews) 's Twitter Profile Photo

ÌPOLÓWÓ:

Tí e bá nífèé sí ÈGÉ òsìngín, tí ó sèsè délè, ní ìlú Ita Oshi, ni Abeokuta.

Ìrìn ogbòn ìséju péré ni láti Ita Oshin wá sí ìgboro ìlú.

E lè kàn sí Alhaji Sheriff lórí èro won.
+2348093596557.

E kàn sí won ní wàrànsésá.

account_circle